DOWNLOAD Logan Ti Ode – Tope Alabi & TY Bello | MP3, Lyrics

DOWNLOAD Logan Ti Ode – Tope Alabi & TY Bello | MP3, Lyrics

Download Tope Alabi & TY Bello Logan Ti Ode mp3 audio

Eminent gospel music singers Tope Alabi & TY Bello released a new illustrious track titled “Logan Ti Ode” along with its video performance.

Download Mp3/Audio Below

Lyrics: Tope Alabi & TY Bello – Logan Ti Ode

Emi mo’un ojumi tiri
Mo mo’un etimi ti gbo
Mo mo’un ojumi tiri
Mo mo’un etimi ti gbo
Logan to gbo iro ayo re o
Mo mo’un aye ma tiwi
Mo mo’un eniyan ma tiso
Won ti pe wa ni agan ri
Bo ya won ti pe o lo’loshi ri
Sugbon logan to de o
Olugbala l’aye mi leto
Sugbon logan to de yi o
Olugbala l’aye e leto
Aye to ti daru tele tele oo
Logan ti o de
Oro ti eniyan ti n fi alufani re
Logan ti o de
Oro ti ko dara ti a ti so si o
Logan ti o de
Oruko ti kin se ti e ta ti pe o
Logan ti o de
Ani logan ti o de o
Olugbala, aye e leto
Logan ti o de o
Olugbala, aye e leto
Logan ti jesu de
Olugbala, l’aye e leto
Ko si oruko ti aye o le peni
Won a ma peni l’agan lona gbogbo
Bo ba lowo l’owo, agan ni
Bo ba bimo o, agan ni
Bo ba t’egbe ko d’agba, agan loje
Sugbon logan ti o de
Sope logan ti o de…

READ ALSO:  DOWNLOAD Tope Alabi – Gratitude | MP3, Lyrics