DOWNLOAD Tope Alabi – Jesu Ore Otito | MP3, Lyrics

DOWNLOAD Tope Alabi – Jesu Ore Otito | MP3, Lyrics

Download Tope Alabi Jesu Ore Otito mp3 audio

Eminent gospel music singer Tope Alabi released a new illustrious track titled “Jesu Ore Otito” along with its video performance.

Tope Alabi is a colossal gospel music soloist whose biography wouldn’t be complete without acknowledging the Grace of God to be a blessing as in dropping this renowned and career-changing song, Jesu Ore Otito.

Download Mp3/Audio Below

Lyrics: Tope Alabi – Jesu Ore Otito

[Verse 1]
Wa sodo re yio gba o
Oun nikan ni mole to tan so kunkun
Oro re iye, o n gba ni la
Ko tun sona miran tole gbani

READ ALSO:  DOWNLOAD Tope Alabi – Tire Ni | MP3, Lyrics

[Chorus]
Jesu jesu ore otito
Jesu kristi iye loro re
Otan mole so kunkun u aye wa
Enito gba jesu loni iye.

[Verse 2]
Wa ma sonu, aye jin na
Oun nikan lole rin o sebute
Aye so kunkun, jesu ni mole
Gbagbo yio mu o debi isimi

[Verse 3]
Faye re fun, fokan re fun
Mase je kona re mo loju re
Oluwa n kan lekun, ore ma se aya
Ayo la o fi ba jesu joba

READ ALSO:  DOWNLOAD Tope Alabi – Ko Si’bi Ti’mole Re Kode | MP3, Lyrics

[Verse 4]
Oun adun ni keru wiwo di itan
Alafia ti aye kori ni
Ifokanbale irorun, eyi to logo
La jogun fawon toluwa gbala