DOWNLOAD Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise | MP3, Lyrics

DOWNLOAD Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise | MP3, Lyrics

Download Tope Alabi Loro Lero Ati Nise mp3 audio

Eminent gospel music singer Tope Alabi released a new illustrious track titled “Loro Lero Ati Nise” along with its video performance.

Tope Alabi is a colossal gospel music soloist whose biography wouldn’t be complete without acknowledging the Grace of God to be a blessing as in dropping this renowned and career-changing song, Loro Lero Ati Nise.

Download Mp3/Audio Below

Lyrics: Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise

Verse 1
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise

READ ALSO:  DOWNLOAD Psalmos – O Ku Itoju Mi Ft Tope Alabi | MP3, Lyrics

Chrous:
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

Verse 2
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise

Verse 3
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise

READ ALSO:  DOWNLOAD Tope Alabi – Jesu Ore Otito | MP3, Lyrics