° Free Download Of This Amazing Song “MP3 Agbara by Tolulope Adediran”
° Genre: Gospel
° Duration: 04:21
° Recorded: 2024
Experience the captivating essence of an amazing recording artist Tolulope Adediran who has just released a remarkable art creation in form of a music titled “Agbara”.
This song is one of the upcoming album project which will comes fully prepared with many amazing tracks while featuring other legendary artist
As you all know, Tolulope Adediran An award-winning artist has really done well in the music domain, All the recently released songs trended across the continent and beyond, that is why this one is a must-listen aswell.
You can’t afford to miss out on a chance to enjoy this soul-lifting song Listen, Download Tolulope Adediran – Agbara Audio & Don’t forget to Share your thoughts using the comment box below
Agbara Lyrics by Tolulope Adediran;
Chorus: Agbára to laju afoju
Agbára to ji oku dide
Agbára to s’agan dolomo o
Nawo Agbára, ko fi tun aye mi se.
Verse1: Owo Agbára re
O’n sise ribiribi
Owo Agbára re
O’n sise igbala o
Owo Agbára re
O’n sise Iyanu
Owo Agbára re
O’n sise o ji oku dide
Nawo Agbára, ko fi tun aye mi se.
Chorus: Agbára to laju afoju
Agbára to ji oku dide
Agbára to s’agan dolomo o
Nawo Agbára, ko fi tun aye mi se.
Verse 2: Agbára laye ati lorun
Lati fi fun o baba
Agbára laye ati lorun
Lati fi fun o baba
Kosi lowo oso o
Komasi lowo aje o
Kosi lowo babalawo
Komasi lowo onisegun o
Nawo Agbára, ko fi tun aye mi se.
Chorus: Agbára to laju afoju
Agbára to ji oku dide
Agbára to s’agan dolomo o
Nawo Agbára, ko fi tun aye mi se.
Jesu lowo re lowa
Baba lowo re lowa
Gbogbo Agbára
Gbogbo Agbára
Jesu lowo re lowa.
Agbára to s’agan dolomo o
Nawo Agbára ko fi tun aye mi se.